Jóṣúà 21:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n fún àwọn ọmọ àlùfáà Áárónì ní ìlú ààbò tí ẹni tó bá pààyàn máa sá lọ,+ ìyẹn Hébúrónì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Líbínà+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, 2 Àwọn Ọba 19:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn tí Rábúṣákè gbọ́ pé ọba Ásíríà ti kúrò ní Lákíṣì,+ ó pa dà sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sì rí i tó ń bá Líbínà jà.+
13 Wọ́n fún àwọn ọmọ àlùfáà Áárónì ní ìlú ààbò tí ẹni tó bá pààyàn máa sá lọ,+ ìyẹn Hébúrónì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Líbínà+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀,
8 Lẹ́yìn tí Rábúṣákè gbọ́ pé ọba Ásíríà ti kúrò ní Lákíṣì,+ ó pa dà sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sì rí i tó ń bá Líbínà jà.+