2 Àwọn Ọba 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nígbà tó kù díẹ̀ tí Jèhófà máa fi ìjì+ gbé Èlíjà+ lọ sí ọ̀run,* Èlíjà àti Èlíṣà+ jáde kúrò ní Gílígálì.+ 2 Àwọn Ọba 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Bí wọ́n ṣe ń rìn lọ, wọ́n ń sọ̀rọ̀, lójijì kẹ̀kẹ́ ẹṣin oníná àti àwọn ẹṣin oníná+ ya àwọn méjèèjì sọ́tọ̀, ìjì sì gbé Èlíjà lọ sí ọ̀run.*+
2 Nígbà tó kù díẹ̀ tí Jèhófà máa fi ìjì+ gbé Èlíjà+ lọ sí ọ̀run,* Èlíjà àti Èlíṣà+ jáde kúrò ní Gílígálì.+
11 Bí wọ́n ṣe ń rìn lọ, wọ́n ń sọ̀rọ̀, lójijì kẹ̀kẹ́ ẹṣin oníná àti àwọn ẹṣin oníná+ ya àwọn méjèèjì sọ́tọ̀, ìjì sì gbé Èlíjà lọ sí ọ̀run.*+