2 Àwọn Ọba 9:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Bí Jèhórámù ṣe rí Jéhù, ó sọ pé: “Ṣé àlàáfíà lo bá wá, Jéhù?” Àmọ́, ó sọ pé: “Àlàáfíà báwo, nígbà tó jẹ́ pé Jésíbẹ́lì+ ìyá rẹ kò jáwọ́ nínú ìṣekúṣe àti ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àjẹ́ rẹ̀?”+
22 Bí Jèhórámù ṣe rí Jéhù, ó sọ pé: “Ṣé àlàáfíà lo bá wá, Jéhù?” Àmọ́, ó sọ pé: “Àlàáfíà báwo, nígbà tó jẹ́ pé Jésíbẹ́lì+ ìyá rẹ kò jáwọ́ nínú ìṣekúṣe àti ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àjẹ́ rẹ̀?”+