-
Ìṣe 12:21-23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Lọ́jọ́ pàtàkì kan, Hẹ́rọ́dù gbé aṣọ ìgúnwà wọ̀, ó jókòó sórí ìjókòó ìdájọ́, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í sọ àsọyé fún gbogbo wọn. 22 Ni àwọn èèyàn tó pé jọ bá bẹ̀rẹ̀ sí í kígbe pé: “Ohùn ọlọ́run ni, kì í ṣe ti èèyàn!” 23 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, áńgẹ́lì Jèhófà* kọ lù ú, nítorí kò fi ògo fún Ọlọ́run, ìdin* jẹ ẹ́, ó sì kú.
-