-
2 Àwọn Ọba 9:20, 21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Lẹ́yìn náà, olùṣọ́ ròyìn pé: “Ó dé ọ̀dọ̀ wọn, ṣùgbọ́n kò tíì pa dà, bó ṣe ń gun kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀ sì dà bíi ti Jéhù ọmọ ọmọ* Nímúṣì, nítorí eré àsápajúdé ló máa ń sá.” 21 Jèhórámù sọ pé: “Di kẹ̀kẹ́ ẹṣin!” Nítorí náà, wọ́n di kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀, Jèhórámù ọba Ísírẹ́lì àti Ahasáyà+ ọba Júdà sì jáde lọ, kálukú nínú kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ láti pàdé Jéhù. Wọ́n bá a pàdé ní ilẹ̀ Nábótì+ ará Jésírẹ́lì.
-