2 Kíróníkà 23:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ní ọdún keje, Jèhóádà gbé ìgbésẹ̀ akin, ó sì bá àwọn olórí ọgọ́rọ̀ọ̀rún ṣe àdéhùn,*+ àwọn ni: Asaráyà ọmọ Jéróhámù, Íṣímáẹ́lì ọmọ Jèhóhánánì, Asaráyà ọmọ Óbédì, Maaseáyà ọmọ Ádáyà àti Élíṣáfátì ọmọ Síkírì.
23 Ní ọdún keje, Jèhóádà gbé ìgbésẹ̀ akin, ó sì bá àwọn olórí ọgọ́rọ̀ọ̀rún ṣe àdéhùn,*+ àwọn ni: Asaráyà ọmọ Jéróhámù, Íṣímáẹ́lì ọmọ Jèhóhánánì, Asaráyà ọmọ Óbédì, Maaseáyà ọmọ Ádáyà àti Élíṣáfátì ọmọ Síkírì.