-
1 Kíróníkà 23:30, 31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Iṣẹ́ wọn ni láti máa dúró ní àràárọ̀ + láti máa dúpẹ́, kí wọ́n sì máa yin Jèhófà, ohun kan náà ni wọ́n sì ń ṣe ní ìrọ̀lẹ́.+ 31 Wọ́n ń ṣèrànwọ́ nígbàkigbà tí wọ́n bá ń rú àwọn ẹbọ sísun sí Jèhófà ní àwọn Sábáàtì,+ ní àwọn òṣùpá tuntun+ àti ní àwọn àsìkò àjọyọ̀,+ gẹ́gẹ́ bí iye àwọn tí òfin sọ nípa àwọn nǹkan yìí, wọ́n sì ń ṣe bẹ́ẹ̀ nígbà gbogbo níwájú Jèhófà.
-