2 Ẹni ọdún méjìlélógún (22) ni Ahasáyà nígbà tó jọba, ọdún kan ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Ataláyà+ ọmọ ọmọ Ómírì.+
3 Òun náà ṣe ohun tí àwọn ará ilé Áhábù ṣe,+ nítorí ìyá rẹ̀ ni agbani-nímọ̀ràn rẹ̀ tó ń gbà á nímọ̀ràn láti máa hùwà burúkú.