ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 12:11, 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Wọ́n á kó owó tí wọ́n kà náà fún àwọn tí wọ́n yàn láti máa bójú tó iṣẹ́ ilé Jèhófà. Àwọn, ní tiwọn á wá san án fún àwọn oníṣẹ́ igi àti àwọn kọ́lékọ́lé tó ń ṣiṣẹ́ ní ilé Jèhófà,+ 12 títí kan àwọn mọlémọlé àti àwọn agbẹ́kùúta. Wọ́n tún ra ẹ̀là gẹdú àti òkúta gbígbẹ́ láti fi ṣàtúnṣe àwọn ibi tó bà jẹ́ lára ilé Jèhófà, wọ́n sì ná owó náà sórí àwọn àtúnṣe míì tó jẹ mọ́ ilé náà.

  • 2 Kíróníkà 34:10, 11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Lẹ́yìn náà, wọ́n kó o fún àwọn tí wọ́n yàn láti máa bójú tó iṣẹ́ ilé Jèhófà. Àwọn tó ń ṣiṣẹ́ nínú ilé Jèhófà sì lò ó láti mú ilé náà bọ̀ sípò àti láti tún un ṣe. 11 Wọ́n kó o fún àwọn oníṣẹ́ ọnà àti àwọn kọ́lékọ́lé láti fi ra òkúta gbígbẹ́ àti àwọn ẹ̀là gẹdú láti fi ṣe àwọn agbóhunró àti àwọn ìtì igi tí wọ́n á fi kọ́ àwọn ilé tí àwọn ọba Júdà ti jẹ́ kó di àwókù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́