Diutarónómì 24:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Ẹ má pa àwọn bàbá torí ohun tí àwọn ọmọ wọn ṣe, ẹ má sì pa àwọn ọmọ torí ohun tí àwọn bàbá wọn ṣe.+ Kí a pa kálukú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.+
16 “Ẹ má pa àwọn bàbá torí ohun tí àwọn ọmọ wọn ṣe, ẹ má sì pa àwọn ọmọ torí ohun tí àwọn bàbá wọn ṣe.+ Kí a pa kálukú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.+