-
2 Kíróníkà 16:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àmọ́, inú bí Ásà sí aríran náà, ó sì fi í sẹ́wọ̀n,* torí ohun tó sọ mú kí Ásà gbaná jẹ. Ní àkókò yẹn kan náà, Ásà bẹ̀rẹ̀ sí í fìyà jẹ àwọn kan lára àwọn èèyàn náà.
-
-
2 Kíróníkà 18:25, 26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ìgbà náà ni ọba Ísírẹ́lì sọ pé: “Ẹ mú Mikáyà, kí ẹ sì fà á lé ọwọ́ Ámọ́nì olórí ìlú àti Jóáṣì ọmọ ọba. 26 Ẹ sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí ọba sọ nìyí: “Ẹ fi ọ̀gbẹ́ni yìí sínú ẹ̀wọ̀n,+ kí ẹ sì máa fún un ní oúnjẹ díẹ̀ àti omi díẹ̀, títí màá fi dé ní àlàáfíà.”’”
-