-
2 Kíróníkà 14:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ásà ṣe ohun tó dára tó sì tọ́ ní ojú Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀.
-
-
2 Kíróníkà 14:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ó sọ fún Júdà pé: “Ẹ jẹ́ ká kọ́ àwọn ìlú yìí, ká sì mọ ògiri àti àwọn ilé gogoro+ yí wọn ká pẹ̀lú àwọn ẹnubodè* àti àwọn ọ̀pá ìdábùú. Nítorí ilẹ̀ náà ṣì wà ní ìkáwọ́ wa, torí a ti wá Jèhófà Ọlọ́run wa. A ti wá a, ó sì ti fún wa ní ìsinmi kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá tó yí wa ká.” Torí náà, wọ́n parí àwọn ohun tí wọ́n ń kọ́.+
-