-
Ẹ́kísódù 30:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Tí wọ́n bá ń lọ sínú àgọ́ ìpàdé tàbí tí wọ́n bá sún mọ́ pẹpẹ láti ṣiṣẹ́, láti fi iná sun ọrẹ kó sì rú èéfín sí Jèhófà, kí wọ́n lo omi náà kí wọ́n má bàa kú.
-