-
2 Àwọn Ọba 16:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ìgbà náà ni Résínì ọba Síríà àti Pékà ọmọ Remaláyà ọba Ísírẹ́lì wá gbógun ja Jerúsálẹ́mù.+ Wọ́n dó ti Áhásì, àmọ́ wọn ò rí ìlú náà gbà. 6 Ní àkókò yẹn, Résínì ọba Síríà gba Élátì + pa dà fún Édómù, lẹ́yìn náà, ó lé àwọn Júù* kúrò ní Élátì. Àwọn ọmọ Édómù wọ Élátì, wọ́n sì ń gbé ibẹ̀ títí di òní yìí.
-