Jeremáyà 44:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Láti ìgbà tí a ò ti rúbọ sí Ọbabìnrin Ọ̀run* mọ́, tí a ò sì da ọrẹ ohun mímu jáde sí i ni a ti ṣaláìní ohun gbogbo, tí idà àti ìyàn sì ti mú kí á ṣègbé.”
18 Láti ìgbà tí a ò ti rúbọ sí Ọbabìnrin Ọ̀run* mọ́, tí a ò sì da ọrẹ ohun mímu jáde sí i ni a ti ṣaláìní ohun gbogbo, tí idà àti ìyàn sì ti mú kí á ṣègbé.”