-
1 Àwọn Ọba 15:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Dáfídì ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Jèhófà, ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀, kò kúrò nínú gbogbo ohun tí Ó pa láṣẹ fún un, àfi nínú ọ̀ràn Ùráyà ọmọ Hétì.+
-