2 Kíróníkà 24:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Wọ́n fi ilé Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wọn sílẹ̀, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í sin àwọn òpó òrìṣà* àti àwọn òrìṣà, tó fi di pé Ọlọ́run bínú* sí Júdà àti Jerúsálẹ́mù nítorí pé wọ́n ti jẹ̀bi.
18 Wọ́n fi ilé Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wọn sílẹ̀, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í sin àwọn òpó òrìṣà* àti àwọn òrìṣà, tó fi di pé Ọlọ́run bínú* sí Júdà àti Jerúsálẹ́mù nítorí pé wọ́n ti jẹ̀bi.