1 Àwọn Ọba 7:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Hírámù+ tún ṣe àwọn bàsíà, àwọn ṣọ́bìrì+ àti àwọn abọ́.+ Bẹ́ẹ̀ ni Hírámù parí gbogbo iṣẹ́ ilé Jèhófà+ tó ṣe fún Ọba Sólómọ́nì, ìyẹn:
40 Hírámù+ tún ṣe àwọn bàsíà, àwọn ṣọ́bìrì+ àti àwọn abọ́.+ Bẹ́ẹ̀ ni Hírámù parí gbogbo iṣẹ́ ilé Jèhófà+ tó ṣe fún Ọba Sólómọ́nì, ìyẹn: