-
2 Kíróníkà 30:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Bákan náà, ọwọ́ Ọlọ́run tòótọ́ wà ní Júdà láti mú wọn ṣọ̀kan* kí wọ́n lè ṣe ohun tí ọba àti àwọn ìjòyè pa láṣẹ, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Jèhófà.
-