2 Kíróníkà 28:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Yàtọ̀ síyẹn, Áhásì kó àwọn nǹkan èlò ilé Ọlọ́run tòótọ́ jọ; ó sì gé àwọn nǹkan èlò ilé Ọlọ́run tòótọ́ sí wẹ́wẹ́,+ ó ti àwọn ilẹ̀kùn ilé Jèhófà pa,+ ó sì ṣe àwọn pẹpẹ fún ara rẹ̀ sí gbogbo igun ọ̀nà Jerúsálẹ́mù.
24 Yàtọ̀ síyẹn, Áhásì kó àwọn nǹkan èlò ilé Ọlọ́run tòótọ́ jọ; ó sì gé àwọn nǹkan èlò ilé Ọlọ́run tòótọ́ sí wẹ́wẹ́,+ ó ti àwọn ilẹ̀kùn ilé Jèhófà pa,+ ó sì ṣe àwọn pẹpẹ fún ara rẹ̀ sí gbogbo igun ọ̀nà Jerúsálẹ́mù.