-
2 Kíróníkà 29:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Àmọ́ kò sí àwọn àlùfáà tó pọ̀ tó láti bó awọ gbogbo ẹran ẹbọ sísun náà, torí náà, àwọn arákùnrin wọn tí wọ́n jẹ́ ọmọ Léfì ràn wọ́n lọ́wọ́+ títí iṣẹ́ náà fi parí àti títí àwọn àlùfáà fi parí yíya ara wọn sí mímọ́,+ nítorí ó jẹ àwọn ọmọ Léfì lọ́kàn* láti ya ara wọn sí mímọ́ ju bó ṣe jẹ àwọn àlùfáà lọ́kàn lọ.
-