-
1 Àwọn Ọba 7:39Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
39 Lẹ́yìn náà, ó gbé kẹ̀kẹ́ ẹrù márùn-ún sí apá ọ̀tún ilé náà àti márùn-ún sí apá òsì ilé náà, ó sì gbé Òkun náà sí apá ọ̀tún ilé náà láàárín gúúsù àti ìlà oòrùn.+
-