-
1 Kíróníkà 26:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 àwọn ọmọ Léfì mẹ́fà ló wà lápá ìlà oòrùn; mẹ́rin lápá àríwá fún ọjọ́ kọ̀ọ̀kan àti mẹ́rin lápá gúúsù fún ọjọ́ kọ̀ọ̀kan; àwọn méjì-méjì sì wà ní àwọn ilé ìkẹ́rùsí;+
-
-
1 Kíróníkà 26:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Bí wọ́n ṣe pín àwọn aṣọ́bodè náà nìyẹn látinú àwọn ọmọ Kórà àti àwọn ọmọ Mérárì.
-