1 Kíróníkà 24:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Bí a ṣe pín àtọmọdọ́mọ àwọn ọmọ Áárónì nìyí: Àwọn ọmọ Áárónì ni Nádábù, Ábíhù,+ Élíásárì àti Ítámárì.+
24 Bí a ṣe pín àtọmọdọ́mọ àwọn ọmọ Áárónì nìyí: Àwọn ọmọ Áárónì ni Nádábù, Ábíhù,+ Élíásárì àti Ítámárì.+