Àìsáyà 45:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ohun tí Jèhófà sọ fún ẹni tó yàn nìyí, fún Kírúsì,+Ẹni tí mo di ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ mú,+Láti tẹ àwọn orílẹ̀-èdè lórí ba níwájú rẹ̀,+Láti gba ohun ìjà* àwọn ọba,Láti ṣí àwọn ilẹ̀kùn aláwẹ́ méjì níwájú rẹ̀,Kí wọ́n má sì ti àwọn ẹnubodè: Dáníẹ́lì 10:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní ọdún kẹta Kírúsì+ ọba Páṣíà, a ṣí ọ̀rọ̀ kan payá fún Dáníẹ́lì, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Bẹtiṣásárì;+ òótọ́ ni ọ̀rọ̀ náà, ó dá lórí ìjàkadì ńlá kan. Ọ̀rọ̀ náà yé e, a sì jẹ́ kí ohun tó rí yé e.
45 Ohun tí Jèhófà sọ fún ẹni tó yàn nìyí, fún Kírúsì,+Ẹni tí mo di ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ mú,+Láti tẹ àwọn orílẹ̀-èdè lórí ba níwájú rẹ̀,+Láti gba ohun ìjà* àwọn ọba,Láti ṣí àwọn ilẹ̀kùn aláwẹ́ méjì níwájú rẹ̀,Kí wọ́n má sì ti àwọn ẹnubodè:
10 Ní ọdún kẹta Kírúsì+ ọba Páṣíà, a ṣí ọ̀rọ̀ kan payá fún Dáníẹ́lì, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Bẹtiṣásárì;+ òótọ́ ni ọ̀rọ̀ náà, ó dá lórí ìjàkadì ńlá kan. Ọ̀rọ̀ náà yé e, a sì jẹ́ kí ohun tó rí yé e.