-
Ẹ́sírà 5:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ẹ̀dà lẹ́tà tí Táténáì gómìnà agbègbè tó wà ní Ìkọjá Odò àti Ṣetari-bósénáì pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀, àwọn gómìnà kéékèèké ní agbègbè tó wà ní Ìkọjá Odò, fi ránṣẹ́ sí Ọba Dáríúsì nìyí;
-