Ẹ́kísódù 12:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “‘Kí ẹ máa ṣe Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú,+ torí ní ọjọ́ yìí gangan, èmi yóò mú ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ* yín kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì. Kí ẹ máa pa ọjọ́ yìí mọ́ jálẹ̀ àwọn ìran yín, ó ti di òfin fún yín títí láé. Léfítíkù 23:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “‘Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù yìí ni Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú+ fún Jèhófà. Ọjọ́ méje ni kí ẹ fi jẹ búrẹ́dì aláìwú.+
17 “‘Kí ẹ máa ṣe Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú,+ torí ní ọjọ́ yìí gangan, èmi yóò mú ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ* yín kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì. Kí ẹ máa pa ọjọ́ yìí mọ́ jálẹ̀ àwọn ìran yín, ó ti di òfin fún yín títí láé.
6 “‘Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù yìí ni Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú+ fún Jèhófà. Ọjọ́ méje ni kí ẹ fi jẹ búrẹ́dì aláìwú.+