Nehemáyà 8:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Torí náà, ní ọjọ́ kìíní oṣù keje,+ àlùfáà Ẹ́sírà mú ìwé Òfin náà wá síwájú àpéjọ*+ àwọn ọkùnrin àti àwọn obìnrin pẹ̀lú gbogbo àwọn tó lè lóye ohun tí wọ́n bá gbọ́. Nehemáyà 12:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àwọn yìí ṣiṣẹ́ nígbà ayé Jóyákímù ọmọ Jéṣúà + ọmọ Jósádákì àti nígbà ayé Nehemáyà gómìnà àti Ẹ́sírà+ tó jẹ́ àlùfáà àti adàwékọ.*
2 Torí náà, ní ọjọ́ kìíní oṣù keje,+ àlùfáà Ẹ́sírà mú ìwé Òfin náà wá síwájú àpéjọ*+ àwọn ọkùnrin àti àwọn obìnrin pẹ̀lú gbogbo àwọn tó lè lóye ohun tí wọ́n bá gbọ́.
26 Àwọn yìí ṣiṣẹ́ nígbà ayé Jóyákímù ọmọ Jéṣúà + ọmọ Jósádákì àti nígbà ayé Nehemáyà gómìnà àti Ẹ́sírà+ tó jẹ́ àlùfáà àti adàwékọ.*