-
Diutarónómì 5:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Mósè wá pe gbogbo ọmọ Ísírẹ́lì jọ, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì, ẹ gbọ́ àwọn ìlànà àti àwọn ìdájọ́ tí mò ń kéde fún yín lónìí, kí ẹ mọ̀ wọ́n, kí ẹ sì rí i pé ẹ̀ ń pa wọ́n mọ́.
-
-
Diutarónómì 17:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ìdájọ́ tí wọ́n bá ṣe ní ibi tí Jèhófà yàn ni kí o tẹ̀ lé. Kí o rí i pé o ṣe gbogbo ohun tí wọ́n bá sọ fún ọ.
-