2 Kíróníkà 15:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nítorí náà, ó lọ bá Ásà, ó sì sọ fún un pé: “Gbọ́ mi, ìwọ Ásà àti gbogbo Júdà àti Bẹ́ńjámínì! Jèhófà á máa wà pẹ̀lú yín tí ẹ ò bá ti fi í sílẹ̀;+ tí ẹ bá sì wá a, á jẹ́ kí ẹ rí òun,+ àmọ́ tí ẹ bá fi í sílẹ̀, á fi yín sílẹ̀.+
2 Nítorí náà, ó lọ bá Ásà, ó sì sọ fún un pé: “Gbọ́ mi, ìwọ Ásà àti gbogbo Júdà àti Bẹ́ńjámínì! Jèhófà á máa wà pẹ̀lú yín tí ẹ ò bá ti fi í sílẹ̀;+ tí ẹ bá sì wá a, á jẹ́ kí ẹ rí òun,+ àmọ́ tí ẹ bá fi í sílẹ̀, á fi yín sílẹ̀.+