-
Diutarónómì 23:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 “Ọmọ Ámónì tàbí ọmọ Móábù kankan ò gbọ́dọ̀ wá sínú ìjọ Jèhófà.+ Àní títí dé ìran wọn kẹwàá, àtọmọdọ́mọ wọn kankan ò gbọ́dọ̀ wá sínú ìjọ Jèhófà láé,
-
-
Diutarónómì 23:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 O ò gbọ́dọ̀ wá ire wọn tàbí ìtẹ̀síwájú wọn ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ.+
-