-
Léfítíkù 5:17, 18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 “Tí ẹnì* kan bá ṣe èyíkéyìí nínú àwọn ohun tí Jèhófà pa láṣẹ pé kí ẹ má ṣe, tó sì tipa bẹ́ẹ̀ ṣẹ̀, bí kò bá tiẹ̀ mọ̀, yóò jìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ torí ó ṣì jẹ̀bi.+ 18 Kó mú àgbò tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá wá fún àlùfáà látinú agbo ẹran, láti fi rú ẹbọ ẹ̀bi,+ kí àgbò náà tó iye tí wọ́n dá lé e. Àlùfáà yóò wá ṣe ètùtù fún un torí àṣìṣe tó ṣe láìmọ̀ọ́mọ̀, yóò sì rí ìdáríjì.
-