Ẹ́sírà 10:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ni Ṣẹkanáyà ọmọ Jéhíélì+ látinú àwọn ọmọ Élámù+ bá sọ fún Ẹ́sírà pé: “A ti hùwà àìṣòótọ́ sí Ọlọ́run wa, bí a ṣe fẹ́ àwọn obìnrin àjèjì* láàárín àwọn èèyàn ilẹ̀ tó yí wa ká.+ Síbẹ̀ náà, ìrètí ṣì wà fún Ísírẹ́lì.
2 Ni Ṣẹkanáyà ọmọ Jéhíélì+ látinú àwọn ọmọ Élámù+ bá sọ fún Ẹ́sírà pé: “A ti hùwà àìṣòótọ́ sí Ọlọ́run wa, bí a ṣe fẹ́ àwọn obìnrin àjèjì* láàárín àwọn èèyàn ilẹ̀ tó yí wa ká.+ Síbẹ̀ náà, ìrètí ṣì wà fún Ísírẹ́lì.