1 Àwọn Ọba 8:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Gbogbo èèyàn Ísírẹ́lì pé jọ síwájú Ọba Sólómọ́nì nígbà àjọyọ̀* ní oṣù Étánímù,* ìyẹn oṣù keje.+