Ẹ́sírà 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ni àwọn èèyàn ilẹ̀ náà bá ń kó ìrẹ̀wẹ̀sì bá àwọn èèyàn Júdà,* wọ́n sì ń mú kí ọkàn wọn domi, kí wọ́n má lè kọ́ ilé náà.+
4 Ni àwọn èèyàn ilẹ̀ náà bá ń kó ìrẹ̀wẹ̀sì bá àwọn èèyàn Júdà,* wọ́n sì ń mú kí ọkàn wọn domi, kí wọ́n má lè kọ́ ilé náà.+