ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 19:46
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 46 Me-jákónì àti Rákónì, ààlà náà sì dojú kọ Jópà.+

  • Jóṣúà 19:48
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 48 Èyí ni ogún ẹ̀yà Dánì ní ìdílé-ìdílé. Èyí sì ni àwọn ìlú náà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.

  • 1 Kíróníkà 22:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Dáfídì tún pèsè irin tó pọ̀ gan-an láti fi ṣe ìṣó ilẹ̀kùn àwọn ẹnubodè àti àwọn ẹ̀mú,* bákan náà, ó pèsè bàbà tó pọ̀ débi pé kò ṣeé wọ̀n+ 4 àti ẹ̀là gẹdú kédárì+ tí kò níye, nítorí àwọn ọmọ Sídónì + àti àwọn ará Tírè+ kó ẹ̀là gẹdú kédárì tó pọ̀ gan-an wá fún Dáfídì.

  • 2 Kíróníkà 2:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Wò ó! Màá pèsè oúnjẹ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ,+ àwọn agégi tó máa gé igi náà, màá fún wọn ní: ọ̀kẹ́ kan (20,000) òṣùwọ̀n kọ́ọ̀* àlìkámà,* ọ̀kẹ́ kan (20,000) òṣùwọ̀n kọ́ọ̀ ọkà bálì, ọ̀kẹ́ kan (20,000) báàtì* wáìnì àti ọ̀kẹ́ kan (20,000) báàtì òróró.”

  • 2 Kíróníkà 2:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 A máa gé àwọn igi láti Lẹ́bánónì,+ bí èyí tí o nílò bá ṣe pọ̀ tó, a ó kó wọn wá sọ́dọ̀ rẹ ní àdìpọ̀ igi tó léfòó, a ó sì kó wọn gba orí òkun wá sí Jópà;+ wàá sì kó wọn lọ sí Jerúsálẹ́mù.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́