Nehemáyà 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Lásìkò náà, Tòbáyà+ ọmọ Ámónì+ tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ sọ pé: “Kódà tí kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ bá gun ohun tí wọ́n ń kọ́, ó máa wó ògiri olókùúta wọn lulẹ̀.”
3 Lásìkò náà, Tòbáyà+ ọmọ Ámónì+ tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ sọ pé: “Kódà tí kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ bá gun ohun tí wọ́n ń kọ́, ó máa wó ògiri olókùúta wọn lulẹ̀.”