Diutarónómì 7:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Má gbọ̀n rìrì nítorí wọn, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ,+ Ọlọ́run tó tóbi ni, tó sì yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù.+ Diutarónómì 10:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí Jèhófà Ọlọ́run yín jẹ́ Ọlọ́run àwọn ọlọ́run+ àti Olúwa àwọn olúwa, Ọlọ́run tó tóbi, tó lágbára, tó sì yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù, tí kì í ṣe ojúsàájú sí ẹnikẹ́ni,+ tí kì í sì í gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀.
21 Má gbọ̀n rìrì nítorí wọn, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ,+ Ọlọ́run tó tóbi ni, tó sì yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù.+
17 Torí Jèhófà Ọlọ́run yín jẹ́ Ọlọ́run àwọn ọlọ́run+ àti Olúwa àwọn olúwa, Ọlọ́run tó tóbi, tó lágbára, tó sì yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù, tí kì í ṣe ojúsàájú sí ẹnikẹ́ni,+ tí kì í sì í gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀.