ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 27:34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Èyí ni àwọn àṣẹ tí Jèhófà pa fún Mósè ní Òkè Sínáì+ pé kó sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

  • Nọ́ńbà 36:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Èyí ni àwọn àṣẹ àti àwọn ìlànà ìdájọ́ tí Jèhófà fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nípasẹ̀ Mósè ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù, lẹ́gbẹ̀ẹ́ Jọ́dánì ní Jẹ́ríkò.+

  • Diutarónómì 12:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 “Èyí ni àwọn ìlànà àti àwọn ìdájọ́ tí ẹ gbọ́dọ̀ rí i pé ẹ̀ ń pa mọ́ ní gbogbo ọjọ́ tí ẹ bá fi wà láàyè lórí ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá yín máa fún yín pé kó di tiyín.

  • Nehemáyà 9:34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Ní ti àwọn ọba wa, àwọn ìjòyè wa, àwọn àlùfáà wa àti àwọn baba ńlá wa, wọn ò pa Òfin rẹ mọ́, wọn ò sì fiyè sí àwọn àṣẹ rẹ tàbí àwọn ìránnilétí* rẹ tí o fi kìlọ̀ fún wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́