Diutarónómì 15:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Rí i pé o ò gbin èrò ibi yìí sọ́kàn pé, ‘Ọdún keje, ọdún ìtúsílẹ̀, ti fẹ́rẹ̀ẹ́ dé,’+ kí o wá ṣahun sí arákùnrin rẹ tó jẹ́ aláìní, kí o má sì fún un ní nǹkan kan. Tó bá fi ẹjọ́ rẹ sun Jèhófà, ó ti di ẹ̀ṣẹ̀ sí ọ lọ́rùn nìyẹn.+
9 Rí i pé o ò gbin èrò ibi yìí sọ́kàn pé, ‘Ọdún keje, ọdún ìtúsílẹ̀, ti fẹ́rẹ̀ẹ́ dé,’+ kí o wá ṣahun sí arákùnrin rẹ tó jẹ́ aláìní, kí o má sì fún un ní nǹkan kan. Tó bá fi ẹjọ́ rẹ sun Jèhófà, ó ti di ẹ̀ṣẹ̀ sí ọ lọ́rùn nìyẹn.+