-
Ẹ́sírà 8:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Àwọn olórí agbo ilé àti àkọsílẹ̀ orúkọ ìdílé àwọn tó tẹ̀ lé mi jáde kúrò ní Bábílónì nígbà ìjọba Ọba Atasásítà nìyí:+
-
-
Ẹ́sírà 8:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 látinú àwọn ọmọ Jóábù, Ọbadáyà ọmọ Jéhíélì, igba ó lé méjìdínlógún (218) ọkùnrin sì wà pẹ̀lú rẹ̀;
-