Nehemáyà 1:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ìwọ Jèhófà, jọ̀ọ́, jẹ́ kí etí rẹ ṣí sí àdúrà ìránṣẹ́ rẹ àti sí àdúrà àwọn ìránṣẹ́ rẹ tí inú wọn ń dùn láti máa bẹ̀rù orúkọ rẹ, jọ̀ọ́, jẹ́ kí ìránṣẹ́ rẹ ṣàṣeyọrí lónìí, kí ọkùnrin yìí sì ṣojú àánú sí mi.”+ Lásìkò yìí, agbọ́tí ọba ni mí.+
11 Ìwọ Jèhófà, jọ̀ọ́, jẹ́ kí etí rẹ ṣí sí àdúrà ìránṣẹ́ rẹ àti sí àdúrà àwọn ìránṣẹ́ rẹ tí inú wọn ń dùn láti máa bẹ̀rù orúkọ rẹ, jọ̀ọ́, jẹ́ kí ìránṣẹ́ rẹ ṣàṣeyọrí lónìí, kí ọkùnrin yìí sì ṣojú àánú sí mi.”+ Lásìkò yìí, agbọ́tí ọba ni mí.+