-
Nehemáyà 11:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ìyókù àwọn tó wà ní Ísírẹ́lì àti àwọn àlùfáà pẹ̀lú àwọn ọmọ Léfì sì wà nínú gbogbo àwọn ìlú míì ní Júdà, kálukú lórí ilẹ̀ tó jogún.*
-