Ẹ́sírà 8:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ní ọjọ́ kẹrin, a wọn fàdákà àti wúrà àti àwọn nǹkan èlò nínú ilé Ọlọ́run wa,+ a sì kó wọn fún Mérémótì+ ọmọ àlùfáà Úríjà, Élíásárì ọmọ Fíníhásì sì wà pẹ̀lú rẹ̀, àwọn ọmọ Léfì tó wà pẹ̀lú wọn ni Jósábádì+ ọmọ Jéṣúà àti Noadáyà ọmọ Bínúì.+ Nehemáyà 11:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 àti Ṣábétáì+ àti Jósábádì,+ látinú àwọn olórí àwọn ọmọ Léfì, tí wọ́n ń bójú tó àwọn iṣẹ́ míì tó jẹ mọ́ ilé Ọlọ́run tòótọ́
33 Ní ọjọ́ kẹrin, a wọn fàdákà àti wúrà àti àwọn nǹkan èlò nínú ilé Ọlọ́run wa,+ a sì kó wọn fún Mérémótì+ ọmọ àlùfáà Úríjà, Élíásárì ọmọ Fíníhásì sì wà pẹ̀lú rẹ̀, àwọn ọmọ Léfì tó wà pẹ̀lú wọn ni Jósábádì+ ọmọ Jéṣúà àti Noadáyà ọmọ Bínúì.+
16 àti Ṣábétáì+ àti Jósábádì,+ látinú àwọn olórí àwọn ọmọ Léfì, tí wọ́n ń bójú tó àwọn iṣẹ́ míì tó jẹ mọ́ ilé Ọlọ́run tòótọ́