Ẹ́sírà 7:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Èyí ni ẹ̀dà lẹ́tà tí Ọba Atasásítà fún Ẹ́sírà tó jẹ́ àlùfáà àti adàwékọ,* ọ̀jáfáfá nínú ẹ̀kọ́* àwọn àṣẹ Jèhófà àti àwọn ìlànà tó fún Ísírẹ́lì:
11 Èyí ni ẹ̀dà lẹ́tà tí Ọba Atasásítà fún Ẹ́sírà tó jẹ́ àlùfáà àti adàwékọ,* ọ̀jáfáfá nínú ẹ̀kọ́* àwọn àṣẹ Jèhófà àti àwọn ìlànà tó fún Ísírẹ́lì: