Ẹ́sítà 9:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ìdí nìyẹn tí àwọn Júù ìgbèríko tó ń gbé ní àwọn ìlú tó wà ní àwọn agbègbè tó jìnnà ṣe fi ọjọ́ kẹrìnlá oṣù Ádárì ṣe ọjọ́ ayọ̀ àti ọjọ́ àsè, ọjọ́ àjọyọ̀ + àti àkókò láti fi oúnjẹ ránṣẹ́ sí ara wọn.+
19 Ìdí nìyẹn tí àwọn Júù ìgbèríko tó ń gbé ní àwọn ìlú tó wà ní àwọn agbègbè tó jìnnà ṣe fi ọjọ́ kẹrìnlá oṣù Ádárì ṣe ọjọ́ ayọ̀ àti ọjọ́ àsè, ọjọ́ àjọyọ̀ + àti àkókò láti fi oúnjẹ ránṣẹ́ sí ara wọn.+