Jẹ́nẹ́sísì 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 O ò ní jẹ́ Ábúrámù* mọ́; orúkọ rẹ yóò di Ábúráhámù,* torí màá mú kí o di bàbá ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè.