Nọ́ńbà 14:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Síbẹ̀, wọ́n ṣorí kunkun,* wọ́n sì lọ sí orí òkè+ náà, àmọ́ àpótí májẹ̀mú Jèhófà àti Mósè kò kúrò ní àárín ibùdó.+
44 Síbẹ̀, wọ́n ṣorí kunkun,* wọ́n sì lọ sí orí òkè+ náà, àmọ́ àpótí májẹ̀mú Jèhófà àti Mósè kò kúrò ní àárín ibùdó.+