-
Nọ́ńbà 14:41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 Àmọ́ Mósè sọ pé: “Kí ló dé tí ẹ̀ ń ṣe kọjá ohun tí Jèhófà pa láṣẹ? Ohun tí ẹ fẹ́ ṣe yìí kò ní yọrí sí rere.