Nọ́ńbà 21:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Lẹ́yìn náà, wọ́n pa dà, wọ́n sì lọ gba Ọ̀nà Báṣánì. Ógù+ ọba Báṣánì àti gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀ sì jáde wá gbéjà kò wọ́n ní Édíréì.+ Nọ́ńbà 21:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í bá òun àti àwọn ọmọ rẹ̀ àti gbogbo èèyàn rẹ̀ jà, títí ìkankan nínú àwọn èèyàn rẹ̀ ò fi ṣẹ́ kù,+ wọ́n sì gba ilẹ̀+ rẹ̀.
33 Lẹ́yìn náà, wọ́n pa dà, wọ́n sì lọ gba Ọ̀nà Báṣánì. Ógù+ ọba Báṣánì àti gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀ sì jáde wá gbéjà kò wọ́n ní Édíréì.+
35 Wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í bá òun àti àwọn ọmọ rẹ̀ àti gbogbo èèyàn rẹ̀ jà, títí ìkankan nínú àwọn èèyàn rẹ̀ ò fi ṣẹ́ kù,+ wọ́n sì gba ilẹ̀+ rẹ̀.